2 Kíróníkà 29:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iye ẹbọ sísun, tí ìjọ ènìyàn mú wá, sì jẹ́ àádọ́rin akọ màlúù, àti ọgọ́rùnún àgbò, àti igba ọ̀dọ́-àgùntàn: gbogbo wọ̀nyí sì ni fún ẹbọ ṣíṣun sí Olúwa.

2 Kíróníkà 29

2 Kíróníkà 29:22-35