2 Kíróníkà 25:27-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. Láti ìgbà tí Ámásíà ti yípadà kúrò láti máa tẹ̀lé Olúwa, wọ́n dìtẹ̀ síi ní Jérúsálẹ́mù, ó sì sálọ sí Lákíṣì ṣùgbọ́n, wọ́n rán àwọn ọkùnrin tẹ̀lé e lọ sí Lákiṣì, wọ́n sì paá síbẹ̀.

28. A gbé e padà pẹ̀lú ẹsin. A sì sin ín pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ ní ìlú ńlá ti Júdà.

2 Kíróníkà 25