2 Kíróníkà 15:17-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. Ṣùgbọ́n a kò mú àwọn ibi gíga náà kúrò ní Ísírẹ́lì; síbẹ̀síbẹ̀ ọkàn Ásà wà ní pípé ní ọjọ́ rẹ̀ gbogbo.

18. Ó sì mú àwọn ohun mímọ́ náà ti baba rẹ̀ àti àwọn ohun mímọ́ ti òun tìkára rẹ̀ tirẹ̀ wá sínú ilé Ọlọ́run, wúrà àti fàdákà àti àwọn ohun èlò náà.

19. Kò sí ogun mọ́ títí fún ọdún márùndínlógójì ti ìjọba Ásà.

2 Kíróníkà 15