1 Tímótíù 3:9-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Kí wọn máa di ohun ìjìnlẹ̀ ìgbàgbọ́ mú pẹ̀lú ọkàn funfun.

10. Kí a kọ́kọ̀ wádìí àwọn wọ̀nyí dájú pẹ̀lú; nígbà náà ni kí a jẹ́ kí wọn ó ṣiṣẹ́ díákónì, bí wọn bá jẹ́ aláìlẹ́gàn.

11. Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni ó yẹ fún àwọn obìnrin láti ni ìwá àgbà, kí wọn má jẹ́ asọ̀rọ̀-ẹni-lẹ́yìn bí kò ṣe aláìrékọjá, olóòótọ́ ní ohun gbogbo.

1 Tímótíù 3