1 Tímótíù 1:19-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Máa ní ìgbàgbọ́ àti ẹ̀rí-ọkàn rere. Àwọn ẹlòmíràn tanù lọ́dọ̀ wọn tí wọ́n sì rí ọkàn ìgbàgbọ́ wọn;

20. Nínú àwọn ẹni tí Híménéù àti Alẹkisáńdérù wà; àwọn tí mo ti fi lé Sàtánì lọ́wọ́, kí a lè kọ́ wọn kí wọn má sọ̀rọ̀-òdì mọ́.

1 Tímótíù 1