1 Tẹsalóníkà 5:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ẹ máa gba ara yín níyànjú, kí ẹ sì máa gbé ara yín ró, gẹ́gẹ́ bí ẹ ti ń ṣe.

1 Tẹsalóníkà 5

1 Tẹsalóníkà 5:10-18