1 Tẹsalóníkà 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí yóò mú kí àwọn tí kì í se Kírísítẹ́nì gbẹ́kẹ̀lé yín àti láti bu ọlá fún yín pẹ̀lú. Bí ẹ bá ṣe bẹ́ẹ̀, ẹ kò ní máa wo ojú ẹnikẹ́ni láti fún yín ni owó tí ẹ ó fi san gbèṣè.

1 Tẹsalóníkà 4

1 Tẹsalóníkà 4:8-18