1 Sámúẹ́lì 7:16-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Láti ọdún dé ọdún, ó lọ yíká láti Bẹ́tẹ́lì dé Gílígálì dé Mísípà, ó sì ń ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì ní gbogbo ibi wọ̀nyí.

17. Ṣùgbọ́n ó máa ń padà sí ilé rẹ̀ ní Rámà, níbí, ó sì tún ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì níbẹ̀, ó sì kọ́ pẹpẹ kan ṣíbẹ̀ fún Olúwa.

1 Sámúẹ́lì 7