1 Sámúẹ́lì 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n gba àpótí ẹ̀rí Olúwa, àwọn ọmọkùnrin Élì méjèèjì sì kú, Hófínì àti Fínéhásì.

1 Sámúẹ́lì 4

1 Sámúẹ́lì 4:1-13