1 Sámúẹ́lì 3:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa wà pẹ̀lú Sámúẹ́lì bí ó ṣe ń dàgbà, kò sì jẹ́ kí ọ̀kan nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ kùnà.

1 Sámúẹ́lì 3

1 Sámúẹ́lì 3:16-21