1 Sámúẹ́lì 27:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì sọ fún Ṣọ́ọ̀lù pé, Dáfídì sá lọ si Gátì: òun kò sì tún wá á kiri mọ́.

1 Sámúẹ́lì 27

1 Sámúẹ́lì 27:1-6