Ákíṣì sì bi í pé, “Níbo ni ẹ̀yin gbé rìn sí lónìí?” Dáfídì sì dáhùn pé, “Síhà gúsù ti Júdà ni, tàbí Síhà gúsù ti Jérámélì,” tàbí “Síhà gúsù ti àwọn ará Kénì.”