1 Sámúẹ́lì 25:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o ti gun orí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí ó sì ń sọ̀kalẹ̀ sí ibi ìkọ̀kọ̀ òkè náà, wò ó, Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì sọ̀kalẹ̀ níwájú rẹ̀; òun sì wá pàdé wọn.

1 Sámúẹ́lì 25

1 Sámúẹ́lì 25:15-24