1 Sámúẹ́lì 24:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gẹ́gẹ́ bí òwe ìgbà àtijọ́ ti wí, ìwá-búburú a máa ti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn búburú jáde wá; ṣùgbọ́n ọwọ́ mi kì yóò sí lára rẹ.

1 Sámúẹ́lì 24

1 Sámúẹ́lì 24:8-16