1 Sámúẹ́lì 23:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì wí fún Dáfídì pé, “Ṣá wò ó, àwọn ará Fílístínì ń bá ará Kéílà jagun, wọ́n sì ja àwọn ilẹ̀ ìpakà lólè.”

1 Sámúẹ́lì 23

1 Sámúẹ́lì 23:1-8