1 Sámúẹ́lì 22:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì ti ibẹ̀ náà lọ sí Mísípa tí Móábù: ó sì wí fún ọba Móábù pé, “Jẹ́ kí baba àti ìyá mi, èmi bẹ̀ ọ́ wá bá ọ gbé, títí èmi yóò fi mọ ohun ti Ọlọ́run yóò ṣe fún mi.”

1 Sámúẹ́lì 22

1 Sámúẹ́lì 22:1-4