1 Sámúẹ́lì 21:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì dìde, o sì sá ni ọjọ́ náà níwájú Ṣọ́ọ̀lù, ó sì lọ sọ́dọ̀ Ákíṣì, ọba Gátì.

1 Sámúẹ́lì 21

1 Sámúẹ́lì 21:6-15