1 Sámúẹ́lì 19:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sọ fún Jónátanì ọmọ rẹ̀ àti gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé kí wọ́n pa Dáfídì. Ṣùgbọ́n Jónátanì fẹ́ràn Dáfídì púpọ̀

1 Sámúẹ́lì 19

1 Sámúẹ́lì 19:1-6