1 Sámúẹ́lì 17:54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì gé orí Fílístínì ó sì gbé e wá sí Jérúsálẹ́mù, ó sì kó àwọn ohun ìjà Fílístínì sìnú àgọ́ tirẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:48-58