1 Sámúẹ́lì 17:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Fílístínì ṣe súnmọ́ iwájú láti pàdé e rẹ̀. Dáfídì yára sáré sí oun náà láti pàdé e rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:46-50