1 Sámúẹ́lì 17:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí pé, “Wá níbí, èmi yóò fi ẹran ara rẹ fún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run jẹ àti fún àwọn ẹranko tí ó wà nínú igbó!”

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:43-53