1 Sámúẹ́lì 17:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì si di idà rẹ̀ mọ́ àwọ̀tẹ́lẹ̀ rẹ̀ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní rìn káàkiri nítorí wí pé kò mọ́ ọ lára.Ó sọ fún Ṣọ́ọ̀lù pé, “Èmi kò le wọ èyí lọ, kò mọ́ mi lára.” Ó sì bọ́ wọn kúrò.

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:34-45