1 Sámúẹ́lì 17:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sá tẹ̀lé e, mo lù ú, mo sì gba àgùntàn náà kúrò lẹ́nu rẹ̀. Nígbà tí ó kọjú sí mi, mo fi irun rẹ̀ gbá a mú, mo sì lù ú mo sì pa á.

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:27-38