1 Sámúẹ́lì 17:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n tún sọ fún un ohun tí wọ́n ti ń sọ, wọ́n sì wí pé, “Èyí ni ohun tí wọn yóò ṣe fún ọkùnrin tí ó bá pa á.”

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:19-34