1 Sámúẹ́lì 16:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésè sì jẹ́ kí Sámà rìn kọjá ní iwájú Sámúẹ́lì, ṣùgbọ́n Sámúẹ́lì wí pé, “Olúwa kò yan ẹni yìí náà.”

1 Sámúẹ́lì 16

1 Sámúẹ́lì 16:4-11