Nígbà náà ni Sámúẹ́lì wí pé, “Mú Ágágì ọba àwọn ará Ámálékì wá fún mi.”Ágágì sì tọ̀ ọ́ wá ní ìgboyà pẹ̀lú èrò pé, “Nítòótọ́ ìkorò ikú ti kọjá.”