1 Sámúẹ́lì 14:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ní àwọn méjèèjì sì fi ara wọn hàn fún ìlú olódi Fílístínì. Àwọn Fílístínì sì wí pé, “Wò ó! Àwọn Hébérù ń fà jáde wá láti inú ihò tí wọ́n fi ara wọn pamọ́ sí.”

1 Sámúẹ́lì 14

1 Sámúẹ́lì 14:4-20