1 Sámúẹ́lì 13:22-23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Bẹ́ẹ̀ ni ọjọ́ ìjà ẹnìkankan nínú àwọn ọmọ ogun tí ó wà pẹ̀lú Ṣọ́ọ̀lù àti Jónátanì kò sì ní idà, tàbí ọ̀kọ̀ ní ọwọ́; àfi Ṣọ́ọ̀lù àti ọmọ rẹ̀ Jónátanì ni wọ́n ni wọ́n.

23. Àwọn ẹgbẹ́ ogun Fílístínì sì ti jáde lọ sí ìkọjá Míkímásì.

1 Sámúẹ́lì 13