1 Pétérù 5:11-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Tírẹ̀ ni ògo àti agbára títí láé (Àmín)

12. Nítorí Sílà, arákùnrin wa olóòtọ́ gẹ́gẹ́ bí mo ti kà á sí, ni mo kọ̀wé kúkurú sí i yín, tí mo ń gbà yín níyànjú, tí mo sì ń jẹ́rìí pé, èyí ni òtítọ́ oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run: ẹ dúró ṣinṣin nínú rẹ̀.

13. Ìjọ tí ń bẹ ní Bábílónì, tí a yàn, pẹ̀lú kí yín, bẹ́ẹ̀ sì ni Máàkù ọmọ mi pẹ̀lú.

14. Ẹ fi ìfẹ́nukònú ìfẹ́ kí ara, yín (Àmín)

1 Pétérù 5