1 Ọba 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdí àwọn asìnrú ti Sólómónì ọba kójọ ni èyí; láti kọ́ ilé Olúwa àti ààfin òun tìkárarẹ̀; Mílò, odi Jérúsálẹ́mù, Hásórì, Mégídò àti Gésérì.

1 Ọba 9

1 Ọba 9:9-16