1 Ọba 7:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì sì tún ṣe gbogbo ohun ọ̀ṣọ́ tí ń ṣe ti ilé Olúwa pẹ̀lú:pẹpẹ wúrà;tabílì wúrà lórí èyí tí àkàrà ìfihàn gbé wà;

1 Ọba 7

1 Ọba 7:39-51