1 Ọba 7:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìkòkò, ọkọ́ àti àwo kòtò.Gbogbo ohun èlò wọ̀nyí tí Hírámù ṣe fún Sólómónì ọba nítorí iṣẹ́ Olúwa sì jẹ́ idẹ dídán.

1 Ọba 7

1 Ọba 7:43-51