1 Ọba 22:52-53 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

52. Ó sì ṣe búburú níwájú Olúwa, nítorí tí ó rìn ní ọ̀nà baba rẹ̀, àti ní ọ̀nà ìyá rẹ̀, àti ní ọ̀nà Jéróbóámù ọmọ Nébátì, tí ó mú Ísírẹ́lì dẹ́ṣẹ̀.

53. Ó sì sin Báálì, ó sì ń bọ Báálì, ó sì mú Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì bínú, gẹ́gẹ́ bí i baba rẹ̀ ti ṣe.

1 Ọba 22