1 Ọba 22:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásáyà ọmọ Áhábù bẹ̀rẹ̀ sí jọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà ní ọdún kẹtàdínlógún Jèhósáfátì ọba Júdà, ó sì jọba ní ọdún méjì lórí Ísírẹ́lì.

1 Ọba 22

1 Ọba 22:45-53