1 Ọba 22:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ẹ sì wí pé, ‘Báyìí ni ọba wí: Ẹ fi eléyìí sínú túbú, kí ẹ sì fi oúnjẹ ìpọ́njú àti omi ìpọ́njú bọ́ ọ, títí èmi yóò fi padà bọ̀ ní àlàáfíà.’ ”

1 Ọba 22

1 Ọba 22:25-30