1 Ọba 22:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Míkáyà sì tún wí pé, “Nítorí náà gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa: Mo rí Olúwa jókòó lórí ìtẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo ogun ọ̀run dúró ní apá ọ̀tún àti ní apá òsì rẹ̀.

1 Ọba 22

1 Ọba 22:11-27