1 Ọba 20:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòlíì náà sì rí ọkùnrin mìíràn, ó sì wí fún un pé, “Jọ̀ ọ́, lù mí.” Bẹ́ẹ̀ ni ọkùnrin náà sì lù ú, ó sì pa á lára.

1 Ọba 20

1 Ọba 20:32-42