1 Ọba 20:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tókù sì sá àsálà lọ sí Áfékì, sínú ìlú tí odi ti wó lù ẹgbàámẹ́talá-lé ẹgbẹ̀rún nínú wọn. Bẹni-Hádádì sì sá lọ sínú ìlú, ó sì fara pamọ́ sínú ìyẹ̀wù.

1 Ọba 20

1 Ọba 20:26-31