1 Ọba 20:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ísírẹ́lì sì jáde lọ, ó sì kọlu àwọn ẹsin àti kẹ̀kẹ́, ó pa àwọn ará Árámù ní ọ̀pọ̀lọpọ̀.

1 Ọba 20

1 Ọba 20:20-26