1 Ọba 2:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà tí ọjọ́ ikú Dáfídì súnmọ́ etílé, ó pàṣẹ fún Sólómónì ọmọ rẹ̀.

2. Ó sì wí pé, “Èmi ti fẹ́ lọ sí ọ̀nà gbogbo ayé, nítorí náà jẹ́ alágbára kí o sì fi ara rẹ hàn bí ọkùnrin,

1 Ọba 2