1 Ọba 19:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbẹ̀, ó lọ sí ibi ihò òkúta, ó sì wọ̀ níbẹ̀.Ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ Èlíjà wá wí pé, “Kí ni ìwọ ń ṣe níhìn-ín yìí, Èlíjà?”

1 Ọba 19

1 Ọba 19:1-11