1 Ọba 19:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíbẹ̀, Èmi ti pa ẹ̀ẹ́dẹ́gbàarin (700) ènìyàn mọ́ fún ara mi ní Ísírẹ́lì, àní gbogbo eékún tí kò ì tíì kúnlẹ̀ fún òrìṣà Báálì, àti gbogbo ẹnu tí kò ì tí ì fi ẹnu kò ó ní ẹnu.”

1 Ọba 19

1 Ọba 19:15-21