1 Ọba 19:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tún fi òróró yan Jéhù ọmọ Nímísì ní ọba lórí Ísírẹ́lì, àti kí o fi òróró yan Èlíṣà ọmọ Sáfátì, ará Ábélí-Méhólà ní wòlíì ní ipò rẹ.

1 Ọba 19

1 Ọba 19:8-21