1 Ọba 18:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbára Olúwa sì ń bẹ lára Èlíjà; ó sì di àmùrè ẹ̀gbẹ́ rẹ, ó sì ṣáré níwájú Áhábù títí dé Jésírẹ́lì.

1 Ọba 18

1 Ọba 18:40-46