1 Ọba 18:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíjà sì wí fún Áhábù pé, “Lọ, jẹ, kí o sì mu, nítorí ìró ọ̀pọ̀lọpọ̀ òjò ń bọ̀.”

1 Ọba 18

1 Ọba 18:35-44