1 Ọba 18:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Omi náà sì ṣàn yí pẹpẹ náà ká, ó sì fi omi kún yàrà náà pẹ̀lú.

1 Ọba 18

1 Ọba 18:30-40