1 Ọba 17:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìkòkò ìyẹ̀fun náà kò ṣófo, kólòbó òróró náà kò gbẹ, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó ti ipa Èlíjà sọ.

1 Ọba 17

1 Ọba 17:11-19