1 Ọba 16:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ómírì sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀ a sì sin ín ní Ṣamáríà. Áhábù ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

1 Ọba 16

1 Ọba 16:25-33