1 Ọba 15:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bááṣà ọmọ Áhíjà ti ilé Ísákárì sì dìtẹ̀ sí i, Bááṣà sì kọlù ú ní Gíbétónì, ìlú àwọn ará Fílístínì, nígbà tí Nádábù àti gbogbo Ísírẹ́lì dó ti Gíbétónì.

1 Ọba 15

1 Ọba 15:18-28