1 Ọba 15:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nádábù ọmọ Jéróbóámù sì jọba lórí Ísírẹ́lì ní ọdún kejì Áṣà ọba Júdà, ó sì jọba lórí Ísírẹ́lì ní ọdún méjì.

1 Ọba 15

1 Ọba 15:17-32